Ǹjẹ́ Nàìjíríà ni Orílẹ̀ èdè kẹfà tí àwọn ènìyàn ti ń gba ẹ̀mí ara wọn jù ní àgbáyé?
Adesanmi Akinsulore, profẹsọ (ọjọgbọn) ní Obafemi Awolowo University (OAU) àti Obafemi Awolowo University Teaching Hospital (OAUTH) (ilé ìwòsàn tí a ti ń kọ nípa ètò ìlera), ní Ilé ifẹ, ní Ìpínlẹ̀ Ọsun, sọ pé Nàìjíríà ni Orílẹ̀ èdè kẹfà tí àwọn ènìyàn ti ń …